Back to Top

Awa gbe o ga Video (MV)

Performed By: Tope Alabi
Length: 4:33
Written by: Tope Alabi, TY Bello, Josh Keyz
[Correct Info]

Tope Alabi - Awa gbe o ga Lyrics
Official

Ore mi ti ki n se ore awon ota mi eeh eeh
Awa gbe o ga
Oluhun ko gun orun a jo si odumare opa tinrin kan le
Awa gbe o ga
Ojo mini mini ti n j'ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pa da bo
Awa gbe o ga
Isale ale oru oru ikawo re lo wa
Awa gbe o ga
Iyin re lo da wa fun olorun
Iyin re lo da wa fun olodumare
Iko ko orun owo lo wa, ibi kan lo n gbe
Iyin re ko ni tan lenu wa
Awa gbe o ga

Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga
Awa ni iran ti n s'aferi re o
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga o
Awa gbe o ga

Agbara lo fi na aye ja lati salu orun wa'ye
Owo re lo fi ina orun ja o po ko ja awon okun

Ojo mini mini ti n j'ara o de yan orun wa wa wa ki igba o pada bo
Isale ale oru oru ikawo re lo wa
Pata pata ologo to n dan gbirin gbirin gbirin gbirin gbirin
Didan ninu ogo ewa Isaju o orun
Awa gbe o ga

Awa ni iran ti n s'aferi re o
Awa gbe o ga
Awa ni iran ti n s'aferi re o
Awa gbe o ga
O ba ni mule ma da ni olowo ori aye
Awa gbe o ga
A a a wa gbe o o o
Awa gbe o ga
A gbe o ga o
A pe o a pe o
Awa gbe o ga
Awa gbe o ga oooooo

Didan ninu ogo ewa isaju o orun
Iyin re lo da wa fun olorun
Iyin re lo da wa fun olodumare
Iyin re ko ni tan lenu wa
Awa gbe o ga
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

Writer: Tope Alabi, TY Bello, Josh Keyz
Copyright: Lyrics © EVENT MANAGEMENT INTERNATIONAL LTD

Back to: Tope Alabi

Tags:
No tags yet