Back to Top

Tinuade - Oluwa Iyanu Lyrics



Tinuade - Oluwa Iyanu Lyrics




OLUWA IYANU LYRICS

Chorus: (lead) 1x
Oluwa iyanu ni (3x) o
Ko s'oba bi ire

All repeat chorus 2x

Verse 1:
Oba orun
Alagbara julo
Aterere ka ye o
Oba to n gbani
Eleje p'ese re
O gba mi lowo ese o
O so mi d'omo Jesu mo dupe o

All Repeat chorus (2x)

Verse 2:
O f'ayemi se'yanu
O fi'se mi se'yanu
Ohun gbogbo ti mo je o
Iyanu ni
Mo wa dupe e se o
F'ore igba gbogbo
Alagbada Ina
Iyanu l'oruko re

Repeat chorus 2x

Interlude----

Chant (lead):
Olorun iyanu dansaki re
Oba a mu ni ko ja ninu Ina
Alagbara to j'alagbara lo
Ipa to bori ipa
Aragba yamu yamu
Eleti gb'aroye

Eh eh eh ah
Ko s'oba bi ire

Call: Jesu (5X) o

Resp: ko s'oba bi ire

Call:Aduro ti ni lojo ogun le o
Resp: ko s'oba bi ire

Call: O gbe ni ni'ja k'eru o b'onija o
Resp: ko s'oba bi ire

Call: A ti ni leyin ko ju ma ti ni
Resp: Ko s'oba bi ire

Lead:
Eh ko s'oba bi ire o oba nla
Ko s'oba bi ire
Oni majeemu mi o
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

OLUWA IYANU LYRICS

Chorus: (lead) 1x
Oluwa iyanu ni (3x) o
Ko s'oba bi ire

All repeat chorus 2x

Verse 1:
Oba orun
Alagbara julo
Aterere ka ye o
Oba to n gbani
Eleje p'ese re
O gba mi lowo ese o
O so mi d'omo Jesu mo dupe o

All Repeat chorus (2x)

Verse 2:
O f'ayemi se'yanu
O fi'se mi se'yanu
Ohun gbogbo ti mo je o
Iyanu ni
Mo wa dupe e se o
F'ore igba gbogbo
Alagbada Ina
Iyanu l'oruko re

Repeat chorus 2x

Interlude----

Chant (lead):
Olorun iyanu dansaki re
Oba a mu ni ko ja ninu Ina
Alagbara to j'alagbara lo
Ipa to bori ipa
Aragba yamu yamu
Eleti gb'aroye

Eh eh eh ah
Ko s'oba bi ire

Call: Jesu (5X) o

Resp: ko s'oba bi ire

Call:Aduro ti ni lojo ogun le o
Resp: ko s'oba bi ire

Call: O gbe ni ni'ja k'eru o b'onija o
Resp: ko s'oba bi ire

Call: A ti ni leyin ko ju ma ti ni
Resp: Ko s'oba bi ire

Lead:
Eh ko s'oba bi ire o oba nla
Ko s'oba bi ire
Oni majeemu mi o
[ Correct these Lyrics ]
Writer: TINUADE ILESANMI
Copyright: Lyrics © ONErpm

Back to: Tinuade



Tinuade - Oluwa Iyanu Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Tinuade
Language: English
Length: 4:22
Written by: TINUADE ILESANMI
[Correct Info]
Tags:
No tags yet