Back to Top

Ranmi Lowo Video (MV)




Performed By: Pastor GbeSoke
Language: English
Length: 4:14
Written by: Akinsina Akinrodoye
[Correct Info]



Pastor GbeSoke - Ranmi Lowo Lyrics




Yeeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Yeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Iranlowo eniyan asan ni
Iranlowo eniyan asan ni
S'eyanu l'aiye mi
S'eyanu l'aiye mi
Ranmilowo Jesu Kristi mi

Yi pada si mi ki o s'aanu fun miiiii
Nitori ko si oluranlowo
Nitori ko si alabaro kan
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa

Yeeeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Yeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Iwo lo'se ranwon fun Mose
Iwo lo'se ranwon f'elijah
Iwo lo'se ranwon fun Hannah
Iwo lo'se ranwon fun Jabesi
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa

Yeeeeee

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Yeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Iwo lo'se ranwon fun Mose
Iwo lo'se ranwon f'elijah
Iwo lo'se ranwon fun Hannah
Iwo lo'se ranwon fun Jabesi
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Yeeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Yeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Iranlowo eniyan asan ni
Iranlowo eniyan asan ni
S'eyanu l'aiye mi
S'eyanu l'aiye mi
Ranmilowo Jesu Kristi mi

Yi pada si mi ki o s'aanu fun miiiii
Nitori ko si oluranlowo
Nitori ko si alabaro kan
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa

Yeeeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Yeeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Iwo lo'se ranwon fun Mose
Iwo lo'se ranwon f'elijah
Iwo lo'se ranwon fun Hannah
Iwo lo'se ranwon fun Jabesi
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa

Yeeeeee

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Yeeeee Oluwa

Ranmi lowo Jesu Kristi mi

Iwo lo'se ranwon fun Mose
Iwo lo'se ranwon f'elijah
Iwo lo'se ranwon fun Hannah
Iwo lo'se ranwon fun Jabesi
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
Ranmi lowo Oluwa
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Akinsina Akinrodoye
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid


Tags:
No tags yet