Abiyamo orun o
Abiyamo ti n ponmo laijabo
Oba to koju simi semi loore
Oke nlanla to n gbe oke mi
Oke kekeke o le duro
Abiyamo lojo isoro
Oba to gba kokoro lowo iku
A toni Igba gbanigbani lojo isoro
Eni kerin ninu ina
Wiwo lule bi ate ileke
Ibere ninu ibere opin ninu opin
O Ji kan lukan pa o pa kan wo kan ye arugbo lailai
Ko seni ti a le fi o we
Iwo loba to n gba dobale awon oba
Koseni to le ba o dog a o
Ko se ni ti a le fi o we baba
Chorus: Na you na you oh lord 2x
After you it's you oh lord
Na you na you oh lord 2x 2nd verse:
Alagbara aye ko lee ba o dogba
Iwo laji pojo iku da o
Iwo to wa loju kan
Ri gbogbo aye o
Orin Lori Omi
Okun fun iyanu re
Koseni ti a le fi o we ( repeat)