Back to Top

Oluwaseun Tẹẹrintẹẹrin - Ki Ijọba Rẹ De Lyrics

Ki ijoba Re de(Oluwaseun Teerinteerin)

Je ki'joba Re de, Kristi k'asee Re bere, je ki'joba Re de e, ki gbogbo aye le mo O.

Won tun mbe won si po, aborisa tun po o, awon ti o bo loju gbamgba, won mborisa ni ikoko, igbiyanju lati pe won wa, sinu agbo Re, awon gan nsa ipa ti won ni, lati po si ninu agbo won, won nse eyi o baba, toripe won ko mo O, won nse eyi o baba, toripe won o da O mo, okunkun bo'le sibe, ni Ile e keferi, dide irawo oroo, dide mase wo mo oo. (Je ko de)

Won tun mbe won si wa, alagbere tun wa o, pansaga, eke, onirera, omuti o mo niwon egbefa, igbiyanju lati pe won wa, sinu agbo Re, awon gan nsa ipa ti won ni, lati wa enia kun ara won, won nse eyi o baba, won ro'pe o ti lo patapata, won nse eyi o baba, won ro'pe o ko nii de mo, akoko na ha da, t'ote yi o pari, ika ati'reje, pelu ifekufe. (gbawa o)

Won tun mbe won si wa, awon olufe ija at'ogun, ko si ifokanbale kankan, lori'leede yi o, bere lati'nu Ile, Ogun ninu ijo Olorun, ka to so ti'nu ilu kookan, titi fi de t'orileede, igbawo niii, ife yo ha j'oba, wonwonyi to'ju su wa, alade iye gbawa o, Ani ijoba ife da? ati t'alafia, 'gbawo ni irira gbogbo, yi o tan bii t'orun (gbawa o)
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

Writer: Olwaseun Teerinteerin
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Oluwaseun Tẹẹrintẹẹrin - Ki Ijọba Rẹ De Video
(Show video at the top of the page)

Tags:
No tags yet