Lo kede ayo na fun gbogbo aiye
P'Omo Olorun segun iku
Fi tiyin-tiyin pel'ayo rohin na
Emi Mimo to gunwa
Oba mi de
Asegun mi de
Ogo ola at'agbara at'pa
F'Odaguntan to gunwa
Iyin Jesu l'awon Angeli nke
T'o wa ra 'raiye pada
Okan soso ajanaku ni Jesu
T'o m'aiye pelu orun
Oba mi de
Asegun mi de
Ogo ola at'agbara at'pa
F'Odaguntan to gunwa
Oba mi de
Asegun mi de
Ogo ola at'agbara at'pa
F'Odaguntan to gunwa
Oba ogo Wole de
Eleruburu ike Wole
Gbogbo gbo idile Jesse Wole
Alapanla
Atorise
Oba mi Abanise
Abani mule ma dani
Adanimagbagbe Wole
Ologo ajimororo