Back to Top

JK - Orin Dafidi Lyrics

JK - Orin Dafidi Lyrics
Official

Wa gba
Wa gba
Wa gba igbala, wa gba iwosan

Show me how to love you more
Titi lailailai I would never love you less

Wo bi na
Ayo nbe fun eni naa
To seti ikun menu mu, s'ori kunkun
Keyin si imoran gbogbo eniyan buruku
Ti ko ba elese rin, ti ko gbo t'elegan
Ba won k'gbekegbe s'oti pe
Kaka bee, ohun Tife ofin oluwa

Lori ofin oluwa l'ohun ti n f'okan ru
S'ele mu, l'owuro, l'osan, titi dale, ati l'oru oganjo
Eyin e lo saa wo, ohun yio dabi igi ti a gbin ti Eti odo
T'on so lakoko boti ye

Ohun gbogbo t'oba dawole, T'oba fawole
Ma'an yori si rere, amo sa, kori bee f'eniyan buruku
Bi afefe ti n fe, fulufulu naa nbe, leni ibi se n te
Eni rere lo ma pe, abo Oluwa kii fe, o ti daju ati best
Orin dafidi ti dorin atunko

Wa gba
Wa gba, wa gba igbala, wa gba iwosan

Sare wa
Kilode t'awon orile ede se n'binu
Won dinu, won gbimopo, gbogbo re asan bansa
Awon Oba aiye, won ti korawon jo
Awon ijoye nko, won doju ko Oba to laiye, to leru, to le ru

Oba mi Oke, olori Oko, o n woran ologbo teku o'nse yeye
Seru ba won, kia paa, o ti lo far
Mo ti f'oba mi je lori Oke mimo, a ti kede re fun araiye gbo
E je lo gbenu dake, e lo bere mi lowo Awon orile ede
Eyin Oba ekogbon e fiberu sinu wa
Ara ilu s'eti gbo, e gba ikilo mimo
Eyin ijoye nko, eyo k'esi wariri, e lo juba f'omo naa k'oto se tan
Awa ti boluwa to, a ti bori a ti fo
Enikeni t'oba woo, a ri iye b'oti to
Ojo ibinu nbo, gbogbo Iberu e sa, Orin dafidi ti dorin atunko

Will I ever understand all you do for me
Will I ever comprehend
Show me how to love you more
Titi lailailai, I would never love you less

Ani se
Oluwa, iwo ni Oluso aguntan gidi gan
N o ni s'alaini, o mu mi, dubule, Lori papa
Lori papa koriko tutu, o mu mi losi, Ibi omi dake roro
Baba o, s'agbara mi dotun
O to mi si ono, o mu mi la okun, ona ododo, oluwa mo dupe
Amo sa, ohun gbogbo ni f'oruko re
Bi mo tile nrin, ninu okunkun, tabi leti iku
N o ni beru rara, se ni para, iwo ni o wa leyin mi

O gbe tabili niwaju ota, nisoju elegan, d'ororo sori mi
Eyin Omo, e lo f'okan bale
Daju daju ire, sa ma tele mi, ohun gbogbo ni ti re
Ati aiku Baale oro, emi ke, lojojumo nile oluwa

[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

Writer: John Kenny
Copyright: Lyrics © VIRAL PLAYLISTS DIGITAL

Back to: JK

JK - Orin Dafidi Video
(Show video at the top of the page)

Performed By: JK
Language: English
Length: 4:20
Written by: John Kenny

Tags:
No tags yet