Iba Iba baba Agba
Iba Iba Arugbo Ojo
Osuba ologo didam
Titi aye la o ma yin o
Ekun oko oke
Ekun oko farao
Alagbada ina asaju ogun keyin ogun
Iba Iba baba Agba
Iba Iba Arugbo Ojo
Osuba Ologo didan
Titi aye la o ma yin o
Ogbamu gbamu oju orun Osee ngbamu
Okan soso ajanakun tin mi Gbo kiji kiji
Akikitan, abubutan
Aso isotan olodumare
Adun darin adun forolo
Arinu rode, olumero okan
Alade ogo
Ologo didan ologo pipe
Eleruniyin, akoda aye
Aseda orun
Oba to le sohun gbogbo ninu
Ohun gbogbo
Osa gan dolomo mefa
Opin okun pupa niya
Aterere kari aye
Aterere kari orun
Ologun oluwa
Jagun jagun mafitibon se
Asaju ogun, akehin ogun
Ajagun ma fi ti bon se
Agbalagba oye
Titi aye la o ma yin
Iba iba baba agbalagba
Abi abi arrugbo lailai
Asuba ologo didan
Titi aye lao ma yin o