Back to Top

Celestial Palm Sunday Hymns Medly (feat. Cxrissysax) Video (MV)




Performed By: Gabriel Olukolu
Language: English
Length: 4:42
Written by: Gabriel Olukolu
[Correct Info]



Gabriel Olukolu - Celestial Palm Sunday Hymns Medly (feat. Cxrissysax) Lyrics




Ẹyọ, Ẹyọ, ẹ ho, ẹ yọ s'Olùgbàlà
Eyo, eyo, e ho, e yo s'Olugbala
Olùgbàlà n g'ẹṣin bọ s'ode aiye
Ọmọ ẹhin nké Hossanah s'ọba wa
Kristi lo mbọ, ẹ wolẹ fún
Ẹ wolẹ fún
Kristi lo mbọ, ẹ wolẹ fún

Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì nkọ Hossanah
Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì ńkọ́ Hossanah
Ẹ wá ká lọ jọ́sìn, Jésù ló jọba
Ẹ wá bá wa jọ́sìn, Jésù ló jọba

Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì nkọ Hossanah
Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì ńkọ́ Hossanah
Ẹ wá ká lọ jọ́sìn, Jésù ló jọba
Ẹ wá bá wa jọ́sìn, Jésù ló jọba

Ará, ẹ bá mi ká lọ
Pàdé Olúwa mi o
Ará, ẹ bá mi ká lọ
Pàdé Olúwa mi o
Ni Jerusalem
Ni Ìlú ayọ̀
Ni Jerusalem
Ni Ìlú ayo

Àwọn Áńgẹ́lì njo
Àwọn Maleka nyọ
Àwọn Áńgẹ́lì njo
Àwọn Maleka nyọ
Nwọn nke Hossanah
S'Ọmọ Dáfídì
Nwọn nke Hossanah
S'Ọmọ Dáfídì
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Ẹyọ, Ẹyọ, ẹ ho, ẹ yọ s'Olùgbàlà
Eyo, eyo, e ho, e yo s'Olugbala
Olùgbàlà n g'ẹṣin bọ s'ode aiye
Ọmọ ẹhin nké Hossanah s'ọba wa
Kristi lo mbọ, ẹ wolẹ fún
Ẹ wolẹ fún
Kristi lo mbọ, ẹ wolẹ fún

Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì nkọ Hossanah
Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì ńkọ́ Hossanah
Ẹ wá ká lọ jọ́sìn, Jésù ló jọba
Ẹ wá bá wa jọ́sìn, Jésù ló jọba

Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì nkọ Hossanah
Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
T'àwọn áńgẹ́lì ńkọ́ Hossanah
Ẹ wá ká lọ jọ́sìn, Jésù ló jọba
Ẹ wá bá wa jọ́sìn, Jésù ló jọba

Ará, ẹ bá mi ká lọ
Pàdé Olúwa mi o
Ará, ẹ bá mi ká lọ
Pàdé Olúwa mi o
Ni Jerusalem
Ni Ìlú ayọ̀
Ni Jerusalem
Ni Ìlú ayo

Àwọn Áńgẹ́lì njo
Àwọn Maleka nyọ
Àwọn Áńgẹ́lì njo
Àwọn Maleka nyọ
Nwọn nke Hossanah
S'Ọmọ Dáfídì
Nwọn nke Hossanah
S'Ọmọ Dáfídì
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Gabriel Olukolu
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid


Tags:
No tags yet