Back to Top

Funke Ilori - Di Mi Mu Lyrics



Funke Ilori - Di Mi Mu Lyrics




Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu
Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu

Be ba bi mi lere ma yaa riwi
Alagbara nsubu ohun ija won segbe
Awon alufa ko wa olorun mo
Awon oluso ti se si olorun
Won nwa kanga omi fun ara won
Kanga fifo ti ko lee momi duro
Iberu Oluwa ko si niwaju won mo

Awon eniyan mi ti sonu ojo tip e
Oluso aguntan ti mu won si na
Won jeki won rin kiri lori oke
Won nlo lati ori oke nla de kekere
Nitori oye oro Olorun ko si ninu won
Ibugbe ododo ati ireti won

Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu
Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu

Bii ago ti kun fun eye beni ile won kun fun etan
Won ndi nla won di oloro joojo
Awon alufa nse akoso labe won
Superficial reader oro Olorun ni won
Eti won nrin o si ti di si otito
Lati kekere titi de nla won
Olojukokoro ni gbogbo won
Won nwo ogbe eniyan misan fere ni Oluwa wi

Won wipe Alafia Alaafia
Nigbati alaafia ko si
Amu itiju ba won sugbon wok o tiju rara
Won wipe oro Olorun mbe lenuwa
Sugbon kalamu eke lo mbe lowo won
Enikini si ntan enikeji je
Won ti ko ahon won lati seke
Toripe won ko lati mo Oluwa

Di mi mu baba di mi mu o
Jare di mi mu o Jesu
Baba di mi mu dopin
Di mi mu baba di mi mu o
Jare di mi mu o Jesu
Baba di mi mu dopin

Social order aye ti yi pada ara e gbo
A ti fi eniyan fun iye rira
Lati ma se ohun ti ko to
Ese ti dofin ara e fura
Aye dogbotan, o ti dakisa
Igba ti yipada bi ewu oga
Ile aye ti di abule kekere
Ona to wo inu aye ko niye
Ona gbooro ona iparun
Jesu Kristi nikan lona otito

Orile ede ndide si orile ede
Ati ile oba si ile oba
Iyan ajakale arun isele nibi pupo
Ina nseyo l'awon orile ede
Gbogbo nkan wonyi ni ipilese iponju
Ese di pupo o di mejila toro
Ife opolopo ti tutu bi imu aja
Aye wonu ijo, ijo ti wonu aye
It doesn't matter ohun lo gbode kan
Di mi mu o, mama je njabo

Ran mi lowo ki mma se so ilepa mi nu
Ki nma se so ibiti mo nlo nu
Ran mi lowo kin ma se so ile ogo nu
Ki nma se so ibi ti mo nlo nu
Ran mi lowo ki mma se so ilepa mi nu
Ki nma se so ibiti mo nlo nu
Ran mi lowo kin ma se so ile ogo nu
Ki nma se so ibi ti mo nlo nu
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.




Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu
Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu

Be ba bi mi lere ma yaa riwi
Alagbara nsubu ohun ija won segbe
Awon alufa ko wa olorun mo
Awon oluso ti se si olorun
Won nwa kanga omi fun ara won
Kanga fifo ti ko lee momi duro
Iberu Oluwa ko si niwaju won mo

Awon eniyan mi ti sonu ojo tip e
Oluso aguntan ti mu won si na
Won jeki won rin kiri lori oke
Won nlo lati ori oke nla de kekere
Nitori oye oro Olorun ko si ninu won
Ibugbe ododo ati ireti won

Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu
Di mi mu o kemi mama subu
Oluwa mama je njabo
Ile aye yi ma nyo o
Di mi mu o ke mi mama subu

Bii ago ti kun fun eye beni ile won kun fun etan
Won ndi nla won di oloro joojo
Awon alufa nse akoso labe won
Superficial reader oro Olorun ni won
Eti won nrin o si ti di si otito
Lati kekere titi de nla won
Olojukokoro ni gbogbo won
Won nwo ogbe eniyan misan fere ni Oluwa wi

Won wipe Alafia Alaafia
Nigbati alaafia ko si
Amu itiju ba won sugbon wok o tiju rara
Won wipe oro Olorun mbe lenuwa
Sugbon kalamu eke lo mbe lowo won
Enikini si ntan enikeji je
Won ti ko ahon won lati seke
Toripe won ko lati mo Oluwa

Di mi mu baba di mi mu o
Jare di mi mu o Jesu
Baba di mi mu dopin
Di mi mu baba di mi mu o
Jare di mi mu o Jesu
Baba di mi mu dopin

Social order aye ti yi pada ara e gbo
A ti fi eniyan fun iye rira
Lati ma se ohun ti ko to
Ese ti dofin ara e fura
Aye dogbotan, o ti dakisa
Igba ti yipada bi ewu oga
Ile aye ti di abule kekere
Ona to wo inu aye ko niye
Ona gbooro ona iparun
Jesu Kristi nikan lona otito

Orile ede ndide si orile ede
Ati ile oba si ile oba
Iyan ajakale arun isele nibi pupo
Ina nseyo l'awon orile ede
Gbogbo nkan wonyi ni ipilese iponju
Ese di pupo o di mejila toro
Ife opolopo ti tutu bi imu aja
Aye wonu ijo, ijo ti wonu aye
It doesn't matter ohun lo gbode kan
Di mi mu o, mama je njabo

Ran mi lowo ki mma se so ilepa mi nu
Ki nma se so ibiti mo nlo nu
Ran mi lowo kin ma se so ile ogo nu
Ki nma se so ibi ti mo nlo nu
Ran mi lowo ki mma se so ilepa mi nu
Ki nma se so ibiti mo nlo nu
Ran mi lowo kin ma se so ile ogo nu
Ki nma se so ibi ti mo nlo nu
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Funke Ilori
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Funke Ilori



Funke Ilori - Di Mi Mu Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Funke Ilori
Language: English
Length: 6:15
Written by: Funke Ilori

Tags:
No tags yet