Back to Top

Pa Egun Re (Remastered) Video (MV)




Performed By: David Oke A.G.S
Length: 4:19
Written by: David Oke
[Correct Info]



David Oke A.G.S - Pa Egun Re (Remastered) Lyrics




Eje Jesu pa egun re ninu aye mi
Eje Jesu mu egun kuro ninu aye mi
Sure fun mi, bukun fun mi fa dun saye mi
Gbadura fun mi Jesu ka ye mi toro

So agbegbe mi di nla
Je ki Orun si ko ro ojo aanu
Irungbin omije ti mo gbin
Je ki n fi ayo kaa
Ki n le fi ogo f'oruko re

Mu ile re se ni kankan Oluwa
Gege bi o ti pinu ni oro re
Da iko lo mi pada pelu owo agbara nla
Je ki n le yo ayo isegun ni gbogbo ona
Ki le so fun gbogbo eniyan wi pe
Oluwa dara si mi

Eje Jesu o Pa egun re
Jesu Kristi Pa Egun re

Pa egun re, pa egun re, Jesu Pa egun Re
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.




Eje Jesu pa egun re ninu aye mi
Eje Jesu mu egun kuro ninu aye mi
Sure fun mi, bukun fun mi fa dun saye mi
Gbadura fun mi Jesu ka ye mi toro

So agbegbe mi di nla
Je ki Orun si ko ro ojo aanu
Irungbin omije ti mo gbin
Je ki n fi ayo kaa
Ki n le fi ogo f'oruko re

Mu ile re se ni kankan Oluwa
Gege bi o ti pinu ni oro re
Da iko lo mi pada pelu owo agbara nla
Je ki n le yo ayo isegun ni gbogbo ona
Ki le so fun gbogbo eniyan wi pe
Oluwa dara si mi

Eje Jesu o Pa egun re
Jesu Kristi Pa Egun re

Pa egun re, pa egun re, Jesu Pa egun Re
[ Correct these Lyrics ]
Writer: David Oke
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid


Tags:
No tags yet