Back to Top

Arugbo Ojo [Album] Video (MV)

Performed By: David G
Length: 5:22
Written by: David Gbenga Olusegun

David G - Arugbo Ojo [Album] Lyrics
Official

Edu mare Oba mi ni
Oba eh eh umm
Mo wole fun o
Alagbada ina Baba mi oo
Mo wole fun o
Ogbe nu wundia sododo
Mo wole fun o
Ato farati bi oke won ni Baba
Mo wole fun o
Arugbo Ojo
Mo wole fun o
Baba awon tio ni baba
Ehh mo wole fun o
Kabi O omasi o Baba mi
Mo wole fun o
Ogbe nu wundia sododo ododo Baba o
Mo wole fun o
Arugbo Ojo
Ehh mo wole fun o mo wole fun o Baba oo mo wole fun o
Ehh ehh Arugbo Ojo
Arabaribitirabata Baba mi oo mo wole fun o Edumare Oba mo wole fun o mo wole fun o
Oba lana Oba loni Baba mi Arugbo Ojo
Mo wole fun o mo wole fun o mo wole fun o mo wole fun o
Arugbo Ojo
Oyigiyigi Alagbada Ina Oba wa mo wole fun o Baba wa ehh mo wole fun o mo wole fun oh oh mo wole fun o
Arugbo Ojo

Kabi O osi oh Baba
Alagbada Ina nio oo Baba
Arugbo Ojo nio ooo Baba
Baba awon ti ko ni baba
Emi Mimo ma nio o Baba
Mimo Mimo ma nio o Baba mi
Eru jeje nio Oluwa Oba
Arugbo Ojo

Baba mi nio ooo Baba
Eleda mi nio Baba
Atorise nio oo Baba mi
Ataye se nio oo Baba
Ehh Atowo se ma nio oo Baba
Oloju Ina nio oo Baba mi
Emi mimo nio ooo
Arugbo Ojo
Arugbo Ojo nio oo Baba
Kinihun eya Judah nio oo Baba

Ehh mo wole fun o
Arugbo Arugbo Ojo
Mo wole fun o ehh mo wole fun o mo wole fun o
Arugbo ojo
Ehh yea mo wole fun o mo wole fun o Baba mi mo wole fun o
Opa Mose Arugbo ojo
Arabaribiti Baba mi o mo wole fun o ohoh mo wole fun o mo wole mo wole fun o
Arugbo ojo Arugbo ojo
Eyin L'Atorise mo wole fun o Eyin L'Atumise mo wole fun o Eyin L'Atunwase mo ma wole fun o Eyin Lameda Awoeda oo
Arugbo Ojo Eyin La Arugbo Ojo
Ope lo pe re oh Baba
Ola lo'la Re O Oba mo wole fun o
Iyin ni mo fun o Baba mi Atobajaiye mo wole fun o
Mo wole fun oo
Mo wole fun oo oh oh
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

Writer: David Gbenga Olusegun
Copyright: Lyrics © EVENT MANAGEMENT INTERNATIONAL LTD, Downtown Music Publishing, Verse One Media LLC

Back to: David G

Tags:
No tags yet