Eyin omo alayo (Joyful children)
Ewa jijo ayo (Let's dance joyfully)
Fun Jehovah Shamma (To Jehovah Shamma)
Oba to wa pelu wa (The King that is with us)
Oni emi o wa pelu yin (He say He'll be with you)
Titi de opin aye (Till the end of the age)
Doxa, itumo ni ogo (Doxa, meaning glory)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Doxa
Oluwa ni oluso agutan mi (The Lord is my Shepherd)
Omumi dubule ni papa oko tutu (He makes me to lie down in green pastures)
Otu okan mi lara (He restores my soul)
Omu mi rin ni ona ododo re (He leads me on the path of righteousness)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Oluwa ni oluso agutan mi (The Lord is my Shepherd)
Omumi dubule ni papa oko tutu (He makes me to lie down in green pastures)
Otu okan mi lara (He restores my soul)
Omu mi rin ni ona ododo re (He leads me on the path of righteousness)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Ogo ogo doxa (Glory Glory doxa)
Doxa
Glory
Ogo ogo ogo ogo (Glory Glory Glory glory)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Ijo e da (Let's dance)
Omo alayo oo (Joyful children)
Mujojo Mujojo (Let's Dance Let's Dance)
Ijo ijo ijo ijo (Dance, Dance, Dance, Dance)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)
Owa pelu mi (He is with me)
Oduro timi o (He stands with me)
Ni gbogbo igba (Every season)
Ni gbogbo ona (In every way)
Oluwa wa pelu mi (The Lord is with me)