Wole wa
Hmmmmmm Ma bo
Oooooooh Eeeeehh Ma bo
Wonu Mi ooo, Ko wa bami soro
Wonu Mi ooo, Ko wa bami soro
O wonu Mose, Mose ba okun soro okun gbo
O wonu Elijah, Elijah ba ina soro ina gbo
O wonu Maria, Maria bi Olugbala Araiye
Wonu Mi ooo, Ko wa bami soro
Iwo ni mo fe, eeeh ninu okan mi oo
Iwo mo ni l'oluwa, waaa bami gbe eeeh
Ko mi lati mo se, Ko mi lati wuwa rere
Ko mi lati se ife re, ni gbogbo ojo aiye mi oo
Iwo ni mo fe oo, ran mi lowo