Back to Top

Bennylee - ARAB LEVEL Lyrics



Bennylee - ARAB LEVEL Lyrics




Bennylee
Iro lasan
Arab level
Xtra pro
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Eye ma pa iro fun wa mo, (Iro nla)
Eye ma ta iro fun wa mo (Iro nla)
Eye ma so isokuso, itankitan
Eye palo fun wa mo (Iro nla)
Edekede ta ba ti gbo
Eye ma tu iro fun wa mo (Iro nla)
Asiri yin ti tu
E ye mama paro fun wa mo (Iro nla)

Eye ma pe Aja lobo Huh
Eye ma pekun ni igala huh
Eye ma shawa logo huh
Anobi tegbewa yi onigbala huh
E le tan won ni hausa, ilorin huh
E tun le tan won ni Igala huh
Awa o kin je fausa Emi n korin
O le pemi ni ijaya (Ijaya)
Alagidi niyin Ah Alakatakiti ni yin
Auzubillah olorun oba ma je ka jiri yin
Awa ti ri itumo n se la de mama tu asiri yin
Gbogbo aye lo ti mo wipe elebo saudi niyin ah
Won Ni Saudi la ti wa huh
Ki ni agbole wa nibe? huh
Awa o kin se omo Allah Huh
A mo agbole wa ni ife huh
Won Lon so kurani kale fuwon
Pelu ede larubawa huh
Ori kejila ese keji ni eri to dajusaka
Ko si lamrud kankan to te awon baba mi do
Afi ole onipata pupa to ji nkan awon baba mi ko
Broda dudu oni lawani
Ye ma seh bi omo Fulani
Ilu elebo lon pebi
Elepanaeleboseh

Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level

Omo ile KEU e lo wa ise se
Go to school get degree get your license eh
Ma fi owuro sere mo nkan to ba fe se
Ise ni omo yoruba n se you better find your way
Omo ile KEU e lo wa ise se
Go to school get degree get your license eh
Ma fi owuro sere mo nkan to ba fe se
Ise ni omo yoruba n se you better find your way
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Bennylee
Iro lasan
Arab level
Xtra pro
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Eye ma pa iro fun wa mo, (Iro nla)
Eye ma ta iro fun wa mo (Iro nla)
Eye ma so isokuso, itankitan
Eye palo fun wa mo (Iro nla)
Edekede ta ba ti gbo
Eye ma tu iro fun wa mo (Iro nla)
Asiri yin ti tu
E ye mama paro fun wa mo (Iro nla)

Eye ma pe Aja lobo Huh
Eye ma pekun ni igala huh
Eye ma shawa logo huh
Anobi tegbewa yi onigbala huh
E le tan won ni hausa, ilorin huh
E tun le tan won ni Igala huh
Awa o kin je fausa Emi n korin
O le pemi ni ijaya (Ijaya)
Alagidi niyin Ah Alakatakiti ni yin
Auzubillah olorun oba ma je ka jiri yin
Awa ti ri itumo n se la de mama tu asiri yin
Gbogbo aye lo ti mo wipe elebo saudi niyin ah
Won Ni Saudi la ti wa huh
Ki ni agbole wa nibe? huh
Awa o kin se omo Allah Huh
A mo agbole wa ni ife huh
Won Lon so kurani kale fuwon
Pelu ede larubawa huh
Ori kejila ese keji ni eri to dajusaka
Ko si lamrud kankan to te awon baba mi do
Afi ole onipata pupa to ji nkan awon baba mi ko
Broda dudu oni lawani
Ye ma seh bi omo Fulani
Ilu elebo lon pebi
Elepanaeleboseh

Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level
Iro lasan ni Arab level
Arab level Arab level

Omo ile KEU e lo wa ise se
Go to school get degree get your license eh
Ma fi owuro sere mo nkan to ba fe se
Ise ni omo yoruba n se you better find your way
Omo ile KEU e lo wa ise se
Go to school get degree get your license eh
Ma fi owuro sere mo nkan to ba fe se
Ise ni omo yoruba n se you better find your way
[ Correct these Lyrics ]
Writer: BENJAMIN ADEWOLA
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Bennylee



Bennylee - ARAB LEVEL Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Bennylee
Language: English
Length: 2:26
Written by: BENJAMIN ADEWOLA
[Correct Info]
Tags:
No tags yet