Back to Top

MY DREAMS Video (MV)

Performed By: Adewale
Language: English
Length: 4:26
Written by: Adewale Adeyeye

Adewale - MY DREAMS Lyrics

Emi ti bawon rinrin ajo temi ko fi ni le waye lasan
Mo fi ti kesari fi fun kesari kemi le simi ogun
Emi ti bawon rinrin ajo temi file ma b'egbe pe o
Mo fi ti kesari fi fun kesari kemi le se rere
Irin ajo temi re, koy'ta mi, o n se yeye
O ni mo fe mo irin ajo t'ore, to de fi n pariwo
Mo fe mo irin ajo t'ore, t'o jaye jaye simi gan
Aye ni koro, o ni gbangba
Aye ni koto, o ni gegele
Orita meta, orita merin ni'salu aye
Bor'eni to ba n lo sona ibe, niko mu e dani
B'o n sare laye koma ma se weyin, oro enu ko lasan
Abo oro la n so feni loye, iyen eeyan to bagbon
Mowi temi temi mo kuro nibe 'yoku dowo e

Anybody can say anything they like
Ni temi
I just want to live all of my dreams
I think you too should live all of your dreams
Mo ti waye naa, mo ma rere je
Eyin Baba ati'ya mo ni e jebure o
Awon to n binu kan ya se pele, kan lo calm
Tori, awon to laye ti ni n ma niso
The Universe is aligning my steps
Emi ma se rere

Kilo fe se laye, tiwon o ni bu e
To ba lowo to dabi Dangote
Won a nibo lo ti rowo, se lo fomo olomo seso
To ba tun lewa, to dabi Ramsey Nouha,
Won a ni sohun nikan nikan ni, eeri o n gberaga
Toba tun kole tori bi aafin oba,
Won a ni kilo ko naa, sio alakori,
Bo salaini, to n wakisa kiri
Won a nile to ti wa, won ki se rere laye
Eyi ni mori, ti mo fi n se temi jeje
One man army, mi o benikan binu
One man mopol, mi o ma beni kan ja o
Awon Kan waye won jadun aye titi
Iyen awon, awon t'aye ye
Awon Kan tun waye won pitan ise kaye
Iyen awon, tan sope taye bawo
Aye ti mo wa mi o ni lo lalai se rere.
Nitemi

[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.

English

Emi ti bawon rinrin ajo temi ko fi ni le waye lasan
Mo fi ti kesari fi fun kesari kemi le simi ogun
Emi ti bawon rinrin ajo temi file ma b'egbe pe o
Mo fi ti kesari fi fun kesari kemi le se rere
Irin ajo temi re, koy'ta mi, o n se yeye
O ni mo fe mo irin ajo t'ore, to de fi n pariwo
Mo fe mo irin ajo t'ore, t'o jaye jaye simi gan
Aye ni koro, o ni gbangba
Aye ni koto, o ni gegele
Orita meta, orita merin ni'salu aye
Bor'eni to ba n lo sona ibe, niko mu e dani
B'o n sare laye koma ma se weyin, oro enu ko lasan
Abo oro la n so feni loye, iyen eeyan to bagbon
Mowi temi temi mo kuro nibe 'yoku dowo e

Anybody can say anything they like
Ni temi
I just want to live all of my dreams
I think you too should live all of your dreams
Mo ti waye naa, mo ma rere je
Eyin Baba ati'ya mo ni e jebure o
Awon to n binu kan ya se pele, kan lo calm
Tori, awon to laye ti ni n ma niso
The Universe is aligning my steps
Emi ma se rere

Kilo fe se laye, tiwon o ni bu e
To ba lowo to dabi Dangote
Won a nibo lo ti rowo, se lo fomo olomo seso
To ba tun lewa, to dabi Ramsey Nouha,
Won a ni sohun nikan nikan ni, eeri o n gberaga
Toba tun kole tori bi aafin oba,
Won a ni kilo ko naa, sio alakori,
Bo salaini, to n wakisa kiri
Won a nile to ti wa, won ki se rere laye
Eyi ni mori, ti mo fi n se temi jeje
One man army, mi o benikan binu
One man mopol, mi o ma beni kan ja o
Awon Kan waye won jadun aye titi
Iyen awon, awon t'aye ye
Awon Kan tun waye won pitan ise kaye
Iyen awon, tan sope taye bawo
Aye ti mo wa mi o ni lo lalai se rere.
Nitemi

I just want to live all of my dreams
I think you too should live all of your dreams
Mo ti waye naa, mo ma rere je
Eyin Baba ati'ya mo ni e jebure o
Awon to n binu kan ya se pele, kan lo calm
Tori, awon to laye ti ni n ma niso
The Universe is aligning my steps
Emi ma se rere

I just want to live all of my dreams
I think you too should live all of your dreams
Mo ti waye naa, mo ma rere je
Eyin Baba ati'ya mo ni e jebure o
Awon to n binu kan ya se pele, kan lo calm
Tori, awon to laye ti ni n ma niso
The Universe is aligning my steps
Emi ma se rere
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Adewale Adeyeye
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Adewale

Tags:
No tags yet