Back to Top

Adejuwon - Eniola (feat. Arabinrinmaria) Lyrics



Adejuwon - Eniola (feat. Arabinrinmaria) Lyrics




O mu mi l'ati'nu ita wa,
O fami mo'ra o somi d'omo,
O ta'mi ororo le mi l'ori o
Mo j'oru ko titun
Mo d'eniola.

Verse 1
Ninu Okukun ni baba ti mu mi wa,
O tan'mole s'ona mi,
O ni ki maa lo,
O f'aso iyi at'ola wo mi oo
Mo wa d'eniola o t'aye n wari fun

Emi eni a ba ta k'afi r'atupa lojosi,
Mo wa d'ajitanna wo
Emi t'aro pe ko le pago o
O se mi l'ogo O damilola
O t'ami ororo lemi l'ori o
Mo wa d'eniola o
T'aye n wari fun

Chr.......

Verse. 2

Okuta t'awon omo'le ko sile,
Lo di pataki igun ile
La t'odo Oluwa ni eyi o
O se Iyanu l'oju wa

Emi eni a ba ta k'afi r'atupa lojosi
Mo wa d'eni aji tanna wo oo
Emi eni ta rope ko le pago lojo yen
Oruko to dara ni Olorun fi pemi

Chrs....... Till fade.
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

O mu mi l'ati'nu ita wa,
O fami mo'ra o somi d'omo,
O ta'mi ororo le mi l'ori o
Mo j'oru ko titun
Mo d'eniola.

Verse 1
Ninu Okukun ni baba ti mu mi wa,
O tan'mole s'ona mi,
O ni ki maa lo,
O f'aso iyi at'ola wo mi oo
Mo wa d'eniola o t'aye n wari fun

Emi eni a ba ta k'afi r'atupa lojosi,
Mo wa d'ajitanna wo
Emi t'aro pe ko le pago o
O se mi l'ogo O damilola
O t'ami ororo lemi l'ori o
Mo wa d'eniola o
T'aye n wari fun

Chr.......

Verse. 2

Okuta t'awon omo'le ko sile,
Lo di pataki igun ile
La t'odo Oluwa ni eyi o
O se Iyanu l'oju wa

Emi eni a ba ta k'afi r'atupa lojosi
Mo wa d'eni aji tanna wo oo
Emi eni ta rope ko le pago lojo yen
Oruko to dara ni Olorun fi pemi

Chrs....... Till fade.
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Kehinde Akinola
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid

Back to: Adejuwon



Adejuwon - Eniola (feat. Arabinrinmaria) Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Adejuwon
Language: English
Length: 4:29
Written by: Kehinde Akinola
[Correct Info]
Tags:
No tags yet