Ọmọ bàbá ni mo jẹ́
Àtúnbí nípa ẹ̀jẹ̀ ẹ rẹ̀
Mo di ẹ̀dá títún
NÍtorí ó kú fún mi
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
Ẹni tí mo jẹ́ tẹ́lẹ̀ ti do o hun Ìgbàgbé
KÍyèsi mo dọmọ titun
Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá
Èmi yìí náà mo ṣákolọ
Mo dẹ̀ ṣe ìfẹ́ inú mi
Èmi yìí náà mo wùwà ìkà
Síbẹ̀sí o forí jì mí
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
Èmi ọmọ tó kú, tó sì tún yè
Èmi ọmọ tó sọnù tí a sì ríi
Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá