Mo bere wo
Mo dide
Molo pomi lodo
Nseni mo gbo ohun awon angeli
Mo reni kan kan
Mo wodi keji
Moba r'esu to'n rin kiri gbere gbere
Oni awon angeli ti tilekun orun
Kin ye gbadura mo
Amo mo gbo ohun
Gbo ohun
Awon angeli ti n k'orin
Gbo ohun
Awon angeli ti n k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin k'orin k'orin
Korin won! Won k'orin ogo
Korin won! Won k'orin ogo
Emi mimo ha ni kin bo bata
Oni ile mimo ni mowa kin kun fope
Kin ye beru mo
O l'Oluwa ti dariji ese mi
Mo gbo fere, mo gbo ilu
Mo b'awon korin toripe
Mogbo duru
Oya gbogbo omo adamo ekorin
Gbo ohun
Awon angeli ti n k'orin
Gbo ohun
Awon angeli ti n k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin k'orin k'orin
Korin won! Won k'orin ogo
Korin won! Won k'orin ogo
Ide mi ti ja
Ide mi ti ja
Idemi ti ja halelluya
Modele ayo
Gbo ohun
Awon angeli ti n k'orin
Gbo ohun
Awon angeli ti n k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin won k'orin
Won k'orin k'orin k'orin
Korin won! Won k'orin ogo
Korin won! Won k'orin ogo
Ogo ni fun Baba
Ati Omo
Ati Emi mimo